AJASSE IPO

www.ajasseipo.webs.com

OLUPO COGNOMEN

OLUPO
Emi Ni omo Olupo alelu
Molentente momu joba
Motalala mo mu joye Ni moje
Eyan ti o ba se ori Olupo pele alowo, abimo, asowo ajere
Abode pade owo aba won naa omo aba won je
Aiyewa a toro bi omi owuro pon
Omi atoro pon ko toro bi omi iyaleta
Nijo ti Olupo N womo ti ko romo
Nijo naa lo wa omo lo si idi ogan
Nigbogbo won se n je Logan Logan l’Oyo Ipo.